Esteri 8

asiko ti Olorun ba fe eniyan tiko ba se, yio ri ifarahan ogo re

Esteri 6:7-7:10

eni ti yio se aanu fun kole sa lai se

Esteri 5:5-6:8

Asilo ore ofe lon se akoba fu julo ni awujo wa loni.

Esteri 4:3-5:4

Akoko ti a da wa fun lati se ohun rere ni akoko ise ti Olorun da wa fun.

Esteri 3:7-4:2

Hamani ni o mu to Oba wipe awon ajoji ngbe pelu won ni ile naa

Esteri 2:13-3:6

ko si oun ija ti a ko si awon omo ju ti yio se rere

Esteri 2:4-15

gege be Olorun ti paalase lati owi Isaiah, awon eniyan naa pada si ile won.

Esteri 1:4-2:3

ni opo igba, ti Olorun ba setan ati gbe eniyan ga, a maa gba ipo fun ipo.

Esteri 1:1-3

niwon igba ti akii se ti aye yi o ye ki a yago fun ise aye logan

2 Korinti 12:14- 13:14

e je alagbara,e je pipe ki e si dagba ninuise isin yin

2 Korinti 12:1-6

Okunrin ti o ni iriri orun keta na ni okunrin kan na tia gbe sokale lati ori odi pelu apere